Jòhánù 13:20 BMY

20 Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo wí fún un yín, Ẹni tí ó bá gba ẹnikẹ́ni tí mo rán, ó gbà mí; Ẹni tí ó bá sì gbà mí, ó gba ẹni tí ó rán mi.”

Ka pipe ipin Jòhánù 13

Wo Jòhánù 13:20 ni o tọ