Jòhánù 13:24 BMY

24 Nítorí náà ni Símónì Pétérù sàpẹrẹ sí i, ó sì wí fún un pé, “Wí fún wa ti ẹni tí o ń sọ.”

Ka pipe ipin Jòhánù 13

Wo Jòhánù 13:24 ni o tọ