Jòhánù 13:34 BMY

34 “Òfin titun kan ni mo fi fún yín, kí ẹ̀yin kí ó fẹ́ ọmọnìkejì yín; gẹ́gẹ́ bí èmi ti fẹ́ràn yín, kí ẹ̀yin kí ó sì lè fẹ́ràn ọmọnìkejì yín.

Ka pipe ipin Jòhánù 13

Wo Jòhánù 13:34 ni o tọ