Jòhánù 13:4 BMY

4 Ó dìde ní ìdí oúnjẹ alẹ́, ó sì fi agbádá rẹ̀ lélẹ̀ ní apákan; nígbà tí ó sì mú asọ ìnura, ó di ara rẹ̀ ní àmùrè.

Ka pipe ipin Jòhánù 13

Wo Jòhánù 13:4 ni o tọ