Jòhánù 14:19 BMY

19 Nígbà díẹ̀ sí i, ayé kì yóò rí mi mọ́; ṣùgbọ́n ẹ̀yin yóò rí mi: nítorí tí èmi wà láàyè, ẹ̀yin ó wà láàyè pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Jòhánù 14

Wo Jòhánù 14:19 ni o tọ