Jòhánù 15:11 BMY

11 Nǹkan wọ̀nyí ni mo ti sọ fún yín, kí ayọ̀ mi kí ó lè wà nínú yín, àti kí ayọ̀ yín kí ó lè kún.

Ka pipe ipin Jòhánù 15

Wo Jòhánù 15:11 ni o tọ