Jòhánù 15:2 BMY

2 Gbogbo ẹ̀ka nínú mi tí kò bá so èso, òun a mú kúrò: gbogbo ẹ̀ka tí ó bá sì so èṣo, òun a wẹ̀ ẹ́ mọ́, kí ó lè so èso sí i.

Ka pipe ipin Jòhánù 15

Wo Jòhánù 15:2 ni o tọ