Jòhánù 15:7 BMY

7 Bí ẹ̀yin bá ń gbé inú mi, tí ọ̀rọ̀ mi bá sì gbé inú yín, ẹ ó bèèrè ohunkóhun tí ẹ bá fẹ́, a ó sì ṣe é fún yín.

Ka pipe ipin Jòhánù 15

Wo Jòhánù 15:7 ni o tọ