Jòhánù 17:1 BMY

1 Nǹkan wọ̀nyí ni Jésù sọ, ó sì gbé ojú rẹ̀ sókè ọ̀run, ó sì wí pé:“Baba, wákàtí náà dé, yin ọmọ rẹ lógo, kí ọmọ rẹ kí ó lè yìn ọ́ lógo pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Jòhánù 17

Wo Jòhánù 17:1 ni o tọ