Jòhánù 17:6 BMY

6 “Èmi ti fi orúkọ rẹ hàn fún àwọn ènìyàn tí ìwọ ti fún mi láti inú ayé wá: tìrẹ ni wọ́n ti jẹ́ rí, ìwọ sì ti fi wọ́n fún mi; wọ́n sì ti pa ọ̀rọ̀ rẹ mọ́.

Ka pipe ipin Jòhánù 17

Wo Jòhánù 17:6 ni o tọ