Jòhánù 18:11 BMY

11 Nítorí náà Jésù wí fún Pétérù pé, “Tẹ idà rẹ bọ inú àkọ̀ rẹ: ago tí baba ti fi fún mi, èmi ó ṣe aláìmu ún bí?”

Ka pipe ipin Jòhánù 18

Wo Jòhánù 18:11 ni o tọ