Jòhánù 18:18 BMY

18 Àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ àti àwọn alaṣẹ́ sì dúró níbẹ̀, àwọn ẹni tí ó ti dáná nítorí òtútù mú, wọ́n sì ń yáná: Pétérù sì dúró pẹ̀lú wọn, ó ń yáná.

Ka pipe ipin Jòhánù 18

Wo Jòhánù 18:18 ni o tọ