Jòhánù 18:23 BMY

23 Jésù dá a lóhùn pé, “Bí mo bá sọ̀rọ̀ búburú, jẹ́rìí sí búburú náà: ṣùgbọ́n bí rere bá ni, èé ṣe tí ìwọ fi ń lù mí?”

Ka pipe ipin Jòhánù 18

Wo Jòhánù 18:23 ni o tọ