Jòhánù 18:33 BMY

33 Nítorí náà Pílátù tún wọ inú gbọ̀ngàn, ìdájọ́ lọ, ó sì pe Jésù, ó sì wí fún un pé, “Ìwọ há ni a ni Ọba àwọn Júù bí?”

Ka pipe ipin Jòhánù 18

Wo Jòhánù 18:33 ni o tọ