Jòhánù 18:35 BMY

35 Pílátù dáhùn wí pé, “Èmi ha jẹ́ Júù bí? Àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè rẹ, àti àwọn olórí àlùfáà ni ó fà ọ́ lé èmi lọ́wọ́: kín ní ìwọ ṣe?”

Ka pipe ipin Jòhánù 18

Wo Jòhánù 18:35 ni o tọ