Jòhánù 18:4 BMY

4 Nítorí náà bí Jésù ti mọ ohun gbogbo tí ń bọ̀ wá bá òun, ó jáde lọ, ó sì wí fún wọn pé, “Ta ni ẹ ń wá?”

Ka pipe ipin Jòhánù 18

Wo Jòhánù 18:4 ni o tọ