Jòhánù 18:40 BMY

40 Nítorí náà gbogbo wọn tún kígbe pé, “Kì í ṣe ọkùnrin yìí, bí kò ṣe Bárábà!” Ọlọ́sà sì ni Bárábà.

Ka pipe ipin Jòhánù 18

Wo Jòhánù 18:40 ni o tọ