Jòhánù 19:2 BMY

2 Àwọn ọmọ ogun sì hun adé ẹ̀gún, wọ́n sì fi dé e ní orí, wọ́n sì fi aṣọ ìgúnwà elésèé àlùkò wọ̀ ọ́.

Ka pipe ipin Jòhánù 19

Wo Jòhánù 19:2 ni o tọ