Jòhánù 19:21 BMY

21 Nítorí náà àwọn olórí àlùfáà àwọn Júù wí fún Pílátù pé, “Má ṣe kọ, ‘Ọba àwọn Júù;’ ṣùgbọ́n pé ọkùnrin yìí wí pé, èmi ni Ọba àwọn Júù.”

Ka pipe ipin Jòhánù 19

Wo Jòhánù 19:21 ni o tọ