Jòhánù 19:26 BMY

26 Nígbà tí Jésù rí ìyá rẹ̀ àti ọmọ-ẹ̀yìn náà dúró, ẹni tí Jésù fẹ́ràn, ó wí fún ìyá rẹ̀ pé, “Obìnrin, wo ọmọ rẹ!”

Ka pipe ipin Jòhánù 19

Wo Jòhánù 19:26 ni o tọ