Jòhánù 19:28 BMY

28 Lẹ́yìn èyí, bí Jésù ti mọ̀ pé, a ti parí ohun gbogbo tán, kí ìwé mímọ́ bà á lè ṣẹ, ó wí pé, “Òrùngbẹ ń gbẹ mí.”

Ka pipe ipin Jòhánù 19

Wo Jòhánù 19:28 ni o tọ