Jòhánù 19:30 BMY

30 Nígbà tí Jésù sì ti gba ọtí kíkan náà, ó wí pé, “Ó parí!” Ó sì tẹ orí rẹ̀ ba, ó jọ̀wọ́ ẹ̀mí rẹ̀.

Ka pipe ipin Jòhánù 19

Wo Jòhánù 19:30 ni o tọ