Jòhánù 19:7 BMY

7 Àwọn Júù dá a lóhùn wí pé, “Àwa ní òfin kan, àti gẹ́gẹ́ bí òfin, wa ó yẹ fún un láti kú, nítorí ó gbà pé ọmọ Ọlọ́run ni òun ń ṣe.”

Ka pipe ipin Jòhánù 19

Wo Jòhánù 19:7 ni o tọ