Jòhánù 2:16 BMY

16 Ó sì wí fún àwọn tí ń ta àdàbà pé, “Ẹ gbé nǹkan wọ̀nyí kúrò níhín; ẹ má ṣe sọ ilé Baba mi di ilé ọjà títà.”

Ka pipe ipin Jòhánù 2

Wo Jòhánù 2:16 ni o tọ