Jòhánù 2:19 BMY

19 Jésù dáhùn ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ wó tẹ́ḿpílì yìí palẹ̀, Èmi ó sì tun un kọ ní ọjọ́ mẹ́ta.”

Ka pipe ipin Jòhánù 2

Wo Jòhánù 2:19 ni o tọ