Jòhánù 2:23 BMY

23 Nígbà tí ó sì wà ní Jérúsálẹ́mù, ní àjọ-ìrékọjá, lákókò àjọ náà, ọ̀pọ̀ ènìyàn gba orúkọ rẹ̀ gbọ́ nígbà tí wọ́n rí iṣẹ́ àmì tí ó ṣe.

Ka pipe ipin Jòhánù 2

Wo Jòhánù 2:23 ni o tọ