Jòhánù 2:9 BMY

9 Olórí àsè náà tọ́ omi tí a sọ di wáìnì wò. Òun kò sì mọ ibi tí ó ti wá, ṣùgbọ́n àwọn ìránṣẹ́ tí ó bu omi náà wá mọ̀. Olórí àsè sì pe ọkọ ìyàwó sí apákan,

Ka pipe ipin Jòhánù 2

Wo Jòhánù 2:9 ni o tọ