Jòhánù 20:1 BMY

1 Ní ọjọ́ kínní ọ̀ṣẹ̀ kùtùkùtù nígbà tí ilẹ̀ kò tíì mọ́ ni Màríà Magídalénè wá sí ibojì, ó sì rí i pé, a ti gbé òkúta kúrò lẹ́nu ibojì.

Ka pipe ipin Jòhánù 20

Wo Jòhánù 20:1 ni o tọ