Jòhánù 20:21 BMY

21 Nítorí náà, Jésù sì tún wí fún wọn pé, “Àlàáfíà fún yín: gẹ́gẹ́ bí Baba ti rán mi, bẹ́ẹ̀ ni èmi sì rán yín.”

Ka pipe ipin Jòhánù 20

Wo Jòhánù 20:21 ni o tọ