Jòhánù 20:29 BMY

29 Jésù wí fún un pé, “Nítorí tí ìwọ rí mi ni ìwọ ṣe gbàgbọ́: alábùkún fún ni àwọn tí kò rí mi, tí wọ́n sì gbàgbọ́!”

Ka pipe ipin Jòhánù 20

Wo Jòhánù 20:29 ni o tọ