22 Jésù wí fún un pé, “Bí èmi bá fẹ́ kí ó dúró títí èmi ó fi dé, kínni èyí jẹ́ sí ọ? Ìwọ máa tọ̀ mí lẹ́yìn.”
Ka pipe ipin Jòhánù 21
Wo Jòhánù 21:22 ni o tọ