Jòhánù 3:11 BMY

11 Lóòótọ́ lóòótọ́ ni mo wí fún ọ, Àwa ń sọ èyí tí àwa mọ̀, a sì ń jẹ́rìí èyí tí àwa ti rí; ẹ̀yin kò sì gba ẹ̀rí wa.

Ka pipe ipin Jòhánù 3

Wo Jòhánù 3:11 ni o tọ