Jòhánù 3:17 BMY

17 Nítorí Ọlọ́run kò rán ọmọ rẹ̀ sí ayé láti dá aráyé lẹ́jọ́; ṣùgbọ́n kí a le ti ipaṣẹ̀ rẹ̀ gba aráyé là.

Ka pipe ipin Jòhánù 3

Wo Jòhánù 3:17 ni o tọ