Jòhánù 3:19 BMY

19 Èyí ni ìdájọ́ náà pé, ìmọ́lẹ̀ wá sí ayé, àwọn ènìyàn sì fẹ́ òkùnkùn ju ìmọ́lẹ̀ lọ, nítorí tí iṣẹ́ wọn burú.

Ka pipe ipin Jòhánù 3

Wo Jòhánù 3:19 ni o tọ