Jòhánù 3:31 BMY

31 “Ẹni tí ó ti òkè wá ju gbogbo ènìyàn lọ; ẹni tí ó ti ayé wá ti ayé ni, a sì máa sọ ohun ti ayé. Ẹni tí ó ti ọ̀run wá ju gbogbo ènìyàn lọ.

Ka pipe ipin Jòhánù 3

Wo Jòhánù 3:31 ni o tọ