Jòhánù 4:33 BMY

33 Nítorí náà ni àwọn ọmọ-èyìn rẹ̀ ń bi ara wọn lérè wí pé, “Ẹnì kan mú ońjẹ fún un wá láti jẹ bí?”

Ka pipe ipin Jòhánù 4

Wo Jòhánù 4:33 ni o tọ