Jòhánù 4:40 BMY

40 Nítorí náà, nígbà tí àwọn ará Samáríà wá sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n rọ̀ ọ́ pé, kí ó wà pẹ̀lú wọn: ó sì dúró fún ijọ́ méjì.

Ka pipe ipin Jòhánù 4

Wo Jòhánù 4:40 ni o tọ