Jòhánù 4:45 BMY

45 Nítorí náà nígbà tí ó dé Gálílì, àwọn ará Gálílì gbà á, nítorí ti wọ́n ti rí ohun gbogbo tí ó ṣe ní Jérúsálẹ́mù nígbà àjọ; nítorí àwọn tìkára wọn lọ sí àjọ pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Jòhánù 4

Wo Jòhánù 4:45 ni o tọ