Jòhánù 5:13 BMY

13 Ẹni tí a mú láradá náà kò sì mọ̀ ẹni tí ó jẹ́ nítorí Jésù ti kúrò níbẹ̀, àwọn ènìyàn púpọ̀ wà níbẹ̀.

Ka pipe ipin Jòhánù 5

Wo Jòhánù 5:13 ni o tọ