Jòhánù 5:2 BMY

2 Adágún omi kan sì wà ní Jérúsálẹ́mù, létí bodè àgùntàn, tí a ń pè ní Bẹtiṣáídà ní èdè Hébérù, tí ó ní ìloro márùn-ún.

Ka pipe ipin Jòhánù 5

Wo Jòhánù 5:2 ni o tọ