Jòhánù 5:39 BMY

39 Ẹ̀yin ń wá ìwé-mímọ́ nítorí ẹ̀yin rò pé nínú wọn ni ẹ̀yin ní ìyè tí kò nípẹ̀kun. Wọ̀nyí sì ni àwọn tí ó ń jẹ́rí mi.

Ka pipe ipin Jòhánù 5

Wo Jòhánù 5:39 ni o tọ