4 Nítorí angẹ́lì a máa sọ̀kalẹ̀ lọ sínú adágún náà, a sì máa rú omi rẹ̀: lẹ́yìn ìgbà tí ó bá ti rú omi náà tan ẹnikẹ́ni tí ó bá kọ́kọ́ wọ inú rẹ̀ a di alára dídá kúrò nínú àrùnkárùn tí ó ní.
Ka pipe ipin Jòhánù 5
Wo Jòhánù 5:4 ni o tọ