Jòhánù 6:13 BMY

13 Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n kó wọn jọ wọ́n sì fi àjẹkù ìṣù àkàrà barle márùn-ún náà kún agbọ̀n méjìlá, èyí tí àwọn tí ó jẹun jẹ kù.

Ka pipe ipin Jòhánù 6

Wo Jòhánù 6:13 ni o tọ