Jòhánù 6:17 BMY

17 Wọ́n sì bọ́ sínú ọkọ̀ ojú omi, wọ́n sì rékọjá òkun lọ sí Kápénámù. Ilẹ̀ sì ti ṣú, Jésù kò sì tí ì dé ọ̀dọ̀ wọn.

Ka pipe ipin Jòhánù 6

Wo Jòhánù 6:17 ni o tọ