Jòhánù 6:35 BMY

35 Jésù wí fún wọn pé, “Èmi ni oúnjẹ ìyè: ẹnikẹ́ni tí ó bá tọ̀ mí wá, ebi kì yóò pa á; ẹni tí ó bá sì gbà mí gbọ́, òrùngbẹ kì yóò gbẹ ẹ́ mọ́ láé.

Ka pipe ipin Jòhánù 6

Wo Jòhánù 6:35 ni o tọ