Jòhánù 6:39 BMY

39 Èyí sì ni ìfẹ́ Baba tí ó rán mi pé ohun gbogbo tí o fi fún mi, kí èmi má ṣe sọ ọ̀kan nù nínú wọn, ṣùgbọ́n kí èmi lè jí i dìde níkẹyìn ọjọ́.

Ka pipe ipin Jòhánù 6

Wo Jòhánù 6:39 ni o tọ