46 Kì í ṣe pé ẹnìkan ti rí Baba bí kò ṣe ẹni tí ó ti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá, òun ni ó ti rí Baba.
Ka pipe ipin Jòhánù 6
Wo Jòhánù 6:46 ni o tọ