Jòhánù 6:52 BMY

52 Nítorí náà ni àwọn Júù ṣe ń bá ara wọn jiyàn, pé, “Ọkùnrin yìí yóò ti ṣe lè fi ara rẹ̀ fún wa láti jẹ?”

Ka pipe ipin Jòhánù 6

Wo Jòhánù 6:52 ni o tọ