Jòhánù 6:58 BMY

58 Èyí sì ni oúnjẹ náà tí ó sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run wá: kì í ṣe bí àwọn baba yín ti jẹ mánà, tí wọ́n sì kú: ẹni tí ó bá jẹ́ oúnjẹ yìí yóò yè láéláé.”

Ka pipe ipin Jòhánù 6

Wo Jòhánù 6:58 ni o tọ