Jòhánù 6:63 BMY

63 Ẹ̀mi ní ń sọni di ààyè; ara kò ní èrè kan; ọ̀rọ̀ wọ̀nyí tí mo sọ fún yín, ẹ̀mí ni, ìyè sì ni.

Ka pipe ipin Jòhánù 6

Wo Jòhánù 6:63 ni o tọ